MultiDiac / yor_train.csv
herwoww's picture
Upload folder using huggingface_hub
893cf10 verified
sentence,root,root_meaning
Ówo tí ó sọ mí ní igi imú ni kò jẹ́ kí n mi dáadáa,ÓWO,BOIL
Abọ́ ayọ́ ni ọmọ náà fi n jẹun,Ayọ́,Aluminum
Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù ní mo já orín náà,Orín,chewing stick
ni wọn mú oyún wúndíá se ní òkò,Òkò,A town in Oyo state
Orogún ìyá Kọ́lá lo ràn-án lọ́wọ́,OROGÚN,RIVAL
Ere ṣíṣá ni iṣẹ́ ẹṣin,ẸSIN,HORSE
Wọ́n dá arákùnrin náà dúró sílé ìwòsàn ní torí ẹ̀ya ara rẹ̀,Ẹ̀ya,Tears
Ìdí tí Gboyega ko se wa sí ibi isẹ ko ye mi,Ìdí,Reason
Ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN ni ko jòkó sí,Ọ̀tún,right
Eku àgó mẹ́ta ni a bá nínú omi inú ada,ÀGÓ,A TYPE OF RAT
Obì inú kókó náà so púpọ̀,Obì,Colanut
Ọwọ́ ọmọ náà yá níbi ọ̀wẹ búbù,Ọ̀wẹ,MORSEL
Ọ̀TÙN jẹ ara olú ìlú ìpínlẹ̀ èkìtì,Ọ̀TÙN,A city in Ekiti
Ọ̀kan lára erè ìdárayá ni bọọlu gbigba wà,Eré,Play/Drama
Ọkan lára àwọn akọni ní lẹ̀ yoruba ni Ajagúnlá tí o tẹ ìlú ìlá do,Ìlá,a town in Osun state
"Èṣù ni Ogbẹni Akintọla yìí o, òun ni ó dá áwọ̀ sílẹ̀ láàárín Ọlá àti Ìbùkún",ÈṢÙ,DEVIL
okó ní ọmọkùnrin ń fi se ọkọ obìnrin,Okó,penis
Mo fẹràn ìlù púpọ̀ níbi àríyá,Ìlù,drum
Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí mo fẹràn jùlọ,Ẹ̀kọ,Local food derived from maize
OLORÌ ọba ìlú mi rẹ̀wá púpọ̀,OLORÌ,QUEEN
Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
Ìlú Ọ̀rẹ̀ ni ìyàwó mi bímọ sí,Ọ̀RẸ̀,"A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA"
Ìgbà ko tọ́ lọ bi orere,Ìgbà,Time
Gbogbo àwọn ọdẹ abúlé wa ti gbára dì láti kojú ìkokò ọdaju náà,ÌKOKÒ,HYENA
"Mo bẹ̀rù ọmọ náà púpọ̀, nítorí pé asa ni",ASA,TALKATIVE
Agbè yìí ti lu nìdí,AGBÈ,"BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER"
Ajá jẹ gbogbo egun náà tán,Egun,Bone
ọkùnrin tó sun rárà fún ọkùnrin ẹgbẹ rẹ̀,Rárà,A type of song/elegy
Àwọn àgbà ló lè yanjú ọ̀rọ̀ yìí,ÀGBÀ,ELDERLY PERSON
"Irọ́ ni Bola n pa fún àwọn òbí rẹ̀, ṣugbọn àbúrò rẹ̀ lo járọ́ rẹ̀",Járọ́,To expose a lie
Pí Padé ni ilẹkun ilé iṣẹ́ wà di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yii,PADÉ,"TO SHUT, TO CLOSE UP"
Ó ti rẹ ẹyẹ agbe yìí débi wípé kò lè fò dáadáa mọ́,AGBE,A TYPE OF BIRD
Iya àgbà ran Fọlákẹ́ ni Erèé l'ọja,Erèé,Beans(coupea)
Baba gbìyànjú láti ré ègún kúrò lórí àwọn ọmọ,Ègún,"Spell, curse"
Olóyè jagun gbìyànjú láti dáàbò bo ìlú rẹ,Jagun,A military title
Ẹranko kò ní ohun méjì tí o fi ń se agbára kọjá ìwo,Ìwo,Animal horn
Ókéré gbádùn ẹyìn jíjẹ,Ẹyìn,palm tree fruit
Ọ̀ọni fi ìrù rẹ na ẹkùn ní ojú,Ìrù,tail
"Tí ẹ kò bá sà àwọn isẹpẹ igi náà dáadáa, ebè kíkọ náà kò ní yá",SÀ,PICK
"Ní aláìsí ìṣẹ̀lẹ̀, kì í sí ìtàn",ÌTÀN,STORY
Ẹ̀re agbabọ́ọ̀lù náà wà ní pápá ẹgbẹ agbabọ́ọ̀lù rẹ̀,Ère,Statue
Owò tí ènìyàn ba mọ ni kí ó tẹra mọ́,Owò,business
Ọmọ náà ní ẹ̀jẹ̀ púpọ̀ lára,Ẹ̀jẹ̀,Blood
"Ọjọ́ tí ẹ bá lọ sí oko, ẹ dákun ẹ bá mi gé okùn agba bọ̀",AGBA,A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST
ìyá ran ọmọ ní Abó ni oja,Abọ́,plate
Ọ̀wẹ tí ẹnu rẹ bá gbà ní kí ó máa bù,Ọ̀wẹ,MORSEL
Ẹ sáré bá Ìyá Ìtùnú mú ife kan wá,IFE,CUP
Lọ sun ilẹ̀ tí mo gbé sí èyìnkùlé,Sun,To burn
Ọmọ ìlú Òró ni ìyàwó mi,ÒRÓ,"A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA"
Egbò náà tí di ọyún sí inú gan-an ni o,ỌYÚN,TUMOR
Àwọn amọ̀kòkò pọ̀ ni abúlé wa,ÌKÒKÒ,CLAY RESERVOIR
Inú igbó ní wón sin òkú ẹni ti o bá ní iké sí,Iké,hunchback
Mo bẹ̀rù awọn ọmọ bẹrẹ púpọ̀,BẸRẸ,"AN AREA IN IBADAN, OYO STATE"
Àwọn Agbè-fún-ọba rí pé àwọn doọ̀là àwọn ọmọ ìlú lọ́wọ́ àwọn ọdanran ni ÀYÈ,ÀYÈ,ALIVE
Ọjà ni Ade ti bá ọrẹ rẹ atijọ pade,Ọjà,market
Mo ti fi ìgbà kan jẹ ejò ỌKÁ rí,ỌKÁ,COBRA
Àwọn olórin fẹràn Abo púpọ̀,Abo,Female
Ilé-Ifè ni ìran Yorùbá ti sẹ̀ wá,IFẸ̀,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní kó Ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ síáyẹ́nsì,Ẹ̀KỌ́,Knowledge
Bàbá naa jẹ́jẹ̀ pe awon kòní na ọmọ náà,Jẹ́jẹ̀,To make a vow
Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
Àgbẹ̀ náà fí inú oko rẹ kí àwọn irú náà le dínkù,Irù,tsetse fly
Olóńgbò tó jẹ́ ẹja mi lo jẹ́ kí n jẹ Àmàlà mi ni àsán,ÀSÁN,EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT
Ìgbà tí Bola jẹun tan ni o sun,Ìgbà,Time
mo nífẹ̀ẹ́ sì ẹran ògúnfe ni jíjẹ,Ẹran,Meat
ÀPÀ ọmọ kìí ni dúkìá tó ní láárí kan pàtó,Apà,Spoiler
Mo nífẹ̀ẹ́ sí kíkọ́ èdè Ẹ̀GBÁ,Ẹ̀GBÁ,NAME OF A TRIBE IN YORÙBÁ KINGDOM
Njẹ o ma wá sí ilé ikẹkọ ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow
Gágá ni ọnà há ni ẹnu ọnà abawole sile igbagbo náà,Gágá,Tightly
Ẹ jẹ́ kí a bọ̀wọ̀ fún Ọ̀gá wa dáadáa,Ọ̀GÁ,MASTER
Ẹní àrá bá pa kìí sun silẹ,Àrá,thunder
Diẹ loku ki ọmọ jabọ́ lẹyìn ìyá ìkókó nígbà tí ọ̀já rẹ tu lojiji,Ọ̀já,Rapper to mount baby
Ẹyẹ agbe mẹ́ta ni mo ṣe alabapade lọ́nà oko,AGBE,A TYPE OF BIRD
Èdè ni o ma ń sọ ìran tí ènìyàn ti wá,Èdè,Language
Wọn pe ẹranko tó ní ìwo ìgbín yọjú,Ìwo,Animal horn
Àwọn Agbè-fún-ọba ní láti pàdé ni ìlú Ìbàdàn,PÀDÉ,TO COME TOGETHER
Rí dájú pé o pe ògèdè sí oúnjẹ kí o jẹ́,Ògèdè,incantation
Àṣà radarada gbáà ni kí ènìyàn máa rin ní ìhòòhò,ÀṢÀ,CULTURE
òkúta tí ọmọ náà jù ORÍ ni o ti bá ewúrẹ́,ORÍ,
Gbé ìkòkò náà bá mi ní ọ̀dẹ̀,Ọ̀DẸ̀,PASSAGE
Àgbò tí ìwo rè bá sẹ́ kò se pa iléyá,Ìwo,Animal horn
Ọdẹ pa ikún jẹ ní oko,Ikún,A kind of Squirrel
Owó ní àkàndùn ti mu ọmọ náà,Ọwọ́,Hand
Ẹṣin ọba ìlú ìgbẹ́kẹ̀lé kú ní àná,ẸSIN,HORSE
Ẹyin meji ni Ade fi sori ounjẹ rẹ̀,Ẹyin,Egg
ỌSÁN ìlù náà já nígbà tí akọrin lòó,Ọsán,One of the rope used to tie talking drum
Akinola n sáré gẹ́gẹ́ bíi ẹ́gbọ́n rè,Gẹ́gẹ́,Exactly
"Ẹ̀tù, ọta ati ààyá ni o wà nínú ìbọn ọdẹ náà",Ààyá,
Ọ̀rọ̀ ẹnu Alarape kò dára tó,Ọ̀RỌ̀,WORDS
Bàbá mi lo kọmi bí a ṣe ń ṣe Ẹ̀TÙ,Ẹ̀TÙ,GUN POWDER
won ti gbe igbá ọsẹ le ọmọ náà lórí ki àṣírí to tu,Igbá,Calabash
Ọbẹ̀ ilá dara fún Ọkùnrin tí àtọ̀ rẹ sàn,Ilá,Okro
Àdá ni ó fi pa ẹranko ẹhànnà náà,ÀDÁ,CUTLASS
"Ọjọ́ tí mo bá tún rí ọ pé o ṣe agbe, mo máa nà ọ́",AGBE,BEGGING
Àlàmú ni oríkì tí ìyà àgbà fún un mi,ÀLÀMÚ,A MALE NAME
Gba ìparí yìí kí o máa fi ra Ekundayọ lórí,ÀWÙJẸ̀,SOFT SPOT
Kòsí ààyá kankan nínú ìbọn bàbá ọdẹ náà mọ́,Ààyá,
Rí dájú pé o lọ sí ilé ìtọ̀ kí o tó sùn,Ìtọ̀,Urine
Gbogbo Igbìyànjú Awẹle láti di aya ni ọ̀dẹ̀ Àyànwande lo jásí asán,ASÁN,VAIN
Ile ẹ̀kọ́ gbogbo nise ti ìlú ìré ni Ariyọ̀ ti kàwé,Ìré,"A town in Osun State, Nigeria"
Ègún ìdílé kò ní sẹ lórí gbogbo wa,Ègún,"Spell, curse"
Mo fún ọmọ ní igba náírà lá ti fi jẹun,Igba,two hundred
"Ẹnití a bá torí tiẹ̀ pa adìẹ, iwe ló máa ń jẹ́",IWE,GIZZARD
Àná ni ọjọ́ìbí mi,Àná,yesterday
Inú òkùn ni mo bá Sọlápé nigba ti mo dé ilé wọn,Òkùn,Darkness
Ọkàn lara ọjà to gbajugbaja ni ọjà Gbági ni ìlú Ìbàdàn jẹ,Ọjà,market
Bọọlu náà ti kọjá ìlà ki adari ayo to fan fere,Ìlà,line
Ètò ìṣúná fún àwọn odi wà lára ohun tí ìjọba mẹnu bà,Odi,dump
Ẹ̀yìn ni olukọ ti na akẹkọ náà,Ẹ̀yìn,Back
Ogún àpò ẹ̀wà kò lé tó wa lò níbi ìnáwó òkú ìyá àgbà,OGÚN,TWENTY
ìjọba kọ́ ilé ìwé ìgbàlódé sí ìlú Òdí,Òdí,A town in bayelsa
"Oṣù tó ń bọ̀, ní ọ̀wẹ̀ yóò kàn mí",Ọ̀wè,A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR
"Ẹ̀sín tí wèrè yóò ṣe, kìí jẹ́ kí ó kú bọ̀rọ̀",Ẹ̀SÍN,SHAME
Pátákó yìí kò sí fún kíkọ ikọkukọ,PÁTÁKÓ,"PLANT, BOARD"
"Èṣù má ṣe mí, ọmọ ẹlòmíràn ni kí o ṣe",ÈṢÙ,DEVIL
Ẹkùn jẹ́ ọ̀kan lára ẹranko tó rẹ wà,Ẹkùn,Leopard
Ẹja nla ni ìwọ̀ ọmọ náà gbé,Ìwọ̀,Hook
Akinyemi se ọgbà fún àwọn ẹran rẹ̀,Ọgbà,Garden
Ogunleke mú ejò ọkà wá sí inú abúlé ni ÀYÈ,ÀYÈ,ALIVE
Ọmọ tí ntà ÒRÍ kiri kọjá ní òwúrọ̀,ÒRÍ,Shea Butter
Àwọn agbófinró fi ìpá dára sí ọ̀daràn náà lára,ÌPÁ,KICK
Ojú egbò náà nílò ìtọ́jú gidigidi,EGBÒ,WOUND
Itan ni Mobolaji fi ṣèse níbi ìjàmbá ọkọ̀,ITAN,THIGH
Ìkokò ńlá kan wà ní agbègbè oko wa nígbà kan,ÌKOKÒ,WOLF
Ẹṣin Ọba ti fi pátákò rẹ gbá akódà lẹ́nu,PÁTÁKÒ,HOOF
"Ìjì kìí jà, kí ó dà omi inú àgbọn nù",ÌJÌ,STORM
Olùkọ́ náà fẹ́ràn láti máa mú Egba dání,ẸGBA,CANE
A ní láti bẹ̀rẹ̀ díẹ̀ kí a lè rí ọ̀nà náà gbà,BẸ̀RẸ̀,BEND
Ara kìí ṣe òkúta ni awọn yorùbá wí,Ara,Body
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mọ odi nítorí Àbò,Àbò,Security
"Ọ̀rọ̀ tí a jọ sọ ní àná, ó ti di ọ̀rọ̀ awo o",AWO,SECRET
Àgbẹ̀ tí ó lọ sí oko tí kò mú ọkọ́ lọ́wọ́ eyín rẹ̀ ni yíò lò,Ọkọ́,Hoe
Adesola sá àsálà fún ẹbọra búburú náà,SÁ,RUN AWAY
Àwọn Oladele pa ỌKÁ ńlá kan ní ọ̀sán yii,ỌKÁ,COBRA
"Díẹ̀ loku ki n tẹ ejò paramọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀, nitori ọgba ni àwọ̀ rẹ̀ ati erupẹ ilẹ̀",Ọgba,Equal
Solape gbọ́dọ̀ dé ìlú Ọ̀yun ni kùtùkùtù ọlá,Ọ̀YUN,A TOWN IN KWARA STATE
Igi osè pọ̀ nínú oko Baba bàbá mi,OSÈ,A TYPE OF TREE
Wo ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN rẹ kí o gbé baagi rẹ,Ọ̀tún,right
A ní láti sà àwọn ìdọ̀tí ẹ̀wà náà dáadáa,SÀ,PICK
Aràn n yọ ọmọ náà lẹnu,Aràn,worm
Ọ̀gá wa ti ń bọ̀ wá sí yàrá ikawe,Ọ̀GÁ,MASTER
Àwọn Talabi ni ṣíṣe ni Ìpínlẹ̀ ògùn ni oṣù tó ń bọ̀,ÒGÙN,A STATE IN NIGERIA
Ìlú Ọ̀TÙN rẹwà púpọ̀ láti gbé,Ọ̀TÙN,A city in Ekiti
"Àrò yẹ nígbà tí Bọ́lá n dáná lọwọ, ọbẹ sì dànù",Àrò,stone meant for cooking
Gbogbo àgbọn tí mọ rà ní ọjà lo tí bàjẹ́,Àgbọn,coconut 🥥
Ìlú Ọ̀yun rọrùn láti gbé púpọ̀,Ọ̀YUN,A TOWN IN KWARA STATE
Ẹyẹ idì náà gbé ọmọ Adìẹ,Idì,Eagle
Àwọn oníṣòwò ìkòkò a máa jèrè púpọ̀ ní ayé àtijọ́,ÌKÒKÒ,LOCAL POT
gbogbo igi afàrà inú oko baami tí dawo tán,Afàrà,Shingle wood
olùkọ́ àgbà ra ọkọ̀ fún ìyàwó rẹ̀,Ọkọ̀,CAR
Gbogbo ilé kí bàbá kú Àbò,Abọ̀,welcome
Ejò isán jẹ́ ejò olóró tí ó burú púpọ̀,ISÁN,A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING)
"Láti le tesiwaju, a nílò ìfẹ́ aisẹtan láàárín wa",ÌFẸ́,LOVE
Àwọn agbábọ́ọ̀lù jẹ́jẹ̀ atilẹyin wọn fún akọ́nimọ̀ọ́gbá tuntun,Jẹ́jẹ̀,To make a vow
Ìkokò kì í fi eegun já afira,ÌKOKÒ,WOLF
Kúnlé ra asọ fún àwọn Òbí rẹ̀,Òbí,parent
òkò tí a sọ mọ ọ̀pẹ ni ọ̀pẹ ṣọ mọ́ ni,Òkò,stone🪨
"Ẹnití ó bá gbé ọkàn lé Ọlọhun, yóò ní ìyè àìnípẹ̀kun",ÌYÈ,LIVE
Ó gbọ́dọ̀ ṣe Ẹ̀rán orin náà dáadáa kí ó tó lè dán mọ ọ lẹ́nu,Ẹ̀rán,Something not to forget
Bí èniyàn kò bá dé oko bàbá ẹnìkan kò le mọ̀ bí o ti fẹ̀ tó,Oko,farm
Gbogbo ìlú lé arákùnrin náà sí ẹ̀yìn ìlú ní torí wípé iké tí o ní,Iké,hunchback
Òní ni owo ọ̀yà yín yóò jẹ́ sísan,OWÓ,Ọ̀YÀ
Ọmọ kékeré kan bú sí Ẹkún láàrín ojú ọ̀nà,Ẹkún,Cry
Adekunle fẹ́ràn kí ó máa jẹun ní orí òró,ÒRÓ,STAND
Àwọn ará ìlú feyikọgbon fẹ́ mọ ìdí ọrọ̀ Agbaakin ìlú naa,ỌRỌ̀,WEALTH
Ọta tán nínú ìbọn awọn olè náà ni wọn bá fi ẹsẹ fẹ́ ẹ,Ọta,Bullet
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ eegún ló wà níbi ayẹyẹ ìfinijoyè,Eegún,masqurade
igi oro ti wó lulẹ,ORO,A TYPE OF TREE
Ìkà ni olópàá to yinbọn mo ọmọ náà,Ìkà,wicked
Ipa wo ni ìwọ là kalẹ̀ fún ọjọ́ iwájú àwọn èwe,IPA,PATH
ìlù bàtá ni wọn lù ni ọjọ́ìbí mi,Bàtá,a type Drumbeat
Ara àwọn ìlú tí o jẹ́ gbaju gbaja ni ìlú ìwó jẹ́,Ìwó,A town in osun state
Kò sí bí àna se kéré tó àna ni àna yíò ma jẹ,Àna,inlaw
Ìkà ni Kunle ti o lẹ okuta mo ọrẹ rẹ,Ìkà,wicked
Eku àgó náà tí lu Pakute,ÀGÓ,A TYPE OF RAT
Ìlú Ọ̀yọ́ ni mo gbé dàgbà,Ọ̀YỌ́,A STATE IN NIGERIA
Bàbá aláwò sọ fún àwọn adigun jalè náà pé kí wọn lọ wa Osé Sango wá,OSÉ,A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS
Aya mi mọ iyán gún,Aya,Wife
Bi ara kò bá rọ OKÙN ara kòlè rọ adiẹ,Okùn,Rope
Àwo mẹ́jọ ni ìyá àgbà sọ wípé mo fọ nígbà tí mo wà ní kékeré,ÀWO,PLATE
Ìjọba gbọ́dọ̀ maa san owó ọ̀yà àwọn òṣìṣẹ́ ni kété tí oṣù bá ti parí,OWÓ,Ọ̀YÀ
Òjò tí ó rọ̀ ni àná tí ṣiṣẹ́ ìyè fún igi náà,ÌYÈ,LIVE
Ṣé o lè tẹ́lẹ̀ mi de Ọ̀rẹ̀ ni Ọ̀tunla,Ọ̀RẸ̀,"A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA"
ìyàwó tí wọ́n fẹ́ láìpẹ́ yìí ti bí ọmọ,Ọmọ,child
Àìsàn ibà ni Ẹ̀fọn máa ń fà lára,Ẹ̀FỌN,MOSQUITO
Ẹ gbé ẹrù náà sí Igun ilé ìdáná,IGUN,CORNER
"A nílò isan ni ori ọmọdé, kí a lè gba ibẹ fún ní abẹ́rẹ́",ISAN,VEIN
Isan méjì ni àwọn dókítà sọ pé ó já ní ọwọ́ ọmọ ganfe naa,ISAN,VEIN
Adewolu ni àyò bàbá rẹ̀,ÀYÒ,FAVORITE
Ẹfọ̀n kúrò ní ẹran àfi Pakute pa,ẸFỌ̀N,BUFFALO
Ọmọ bíbí ilú ìlá ni oga ọlọ́pàá lorile ede Nigeria tẹlẹ rí,Ìlá,a town in Osun state
Ilé ọlá dára púpọ̀ láti gbé,Ọlá,wealth
Ọwọ́ tẹ awọn olè ti wọn n da ilu Ọ̀tà láàmú,Ọ̀tà,"A town in Ogun State, Nigeria"
Ẹni tí ó ni èkù lo ni ọ̀bẹ,ÈKÙ,CUTLASS/KNIFE HANDLE
Ọpẹ́ tí ẹ dá yẹn kéré jọjọ,ỌPẸ́,THANKS
Ọ̀já kan ṣoṣo tí ìyá Ìbejí rà logo pọn àwọn ọmọ rẹ mẹrẹrin,Ọ̀já,Rapper to mount baby
ọdún kẹta nìyí tí mo ti ń lo ajọ̀ mi,AJỌ̀,SIEVE
Igbà lo já ti akọ̀pẹ náà se kan,Igbà,rope use to climb palm tree
Mo Sùn ní èbá ọ̀nà lànà,Sùn,Sleep
Mọ gbàgbé láti ranmi létí ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow
"Bí ògiri Adio kò bá lanu, aláàmù Olusegun kò lè wọ ibẹ",ALÁÀMÙ,LIZARD
Ire ni ojú owó n rí,Ire,Goodness
Agbe sise kò yẹ ọmọlúwàbí rárá,AGBE,BEGGING
Fi ÒRÍ pa ara rẹ kí ó má dàn-án,ÒRÍ,Shea Butter
Mo rán ọmọ ní Obì àti orógbó,Obì,Colanut
ọkọ́ jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀,Ọkọ́,Hoe
Ìjì tí ó jà ní alẹ́ àná ni agbára púpọ̀,ÌJÌ,STORM
Igi Osè kì í pẹ́ gbabode,OSÈ,A TYPE OF TREE
Adesoji kò mọ iye owó tí ó kó pamọ́ mọ́,IYE,NUMBER
"Àwọn olórin fi ijo sí, nígbà tí àwon oníbàtá dá wọn lára mi",Bàtá,a type Drumbeat
Rí dájú pé o fọ ẹsẹ̀ kí o to wọlé,Ẹsẹ̀,leg
Ọwọ́ Bukola ni orógùn yìí tí kán sí méjì,ORÓGÙN,"TURNING STICK, TURNER"
Opamade nífẹ̀ẹ́ sí ilà kẹ́kẹ́ ju àbàjà lọ,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
Kabiyesi náà fí olá jiyọ̀ láàfin,Ọlá,wealth
Gbogbo nkan há gágá fún Adé bíi ọjọ mẹta sẹyìn,Gágá,Tightly
Yorùbá ní ìṣẹ́ kìí déédé ṣẹ bí o bá nídìí,Ìṣẹ́,poverty
Ọ̀mọ tí wọ́n lò lára ilé náà kòtó,Ọ̀mọ,A builder of wall
Ọbẹ̀ ẹyìn dun jẹ iyán,Ẹyìn,palm tree fruit
Mọ fe ra agbọ̀n ní ọjà ní ọlà,Agbọ̀n,Basket
Ilà àbàjà ni won nkọ ni ilu Òwu,Ilà,triber mark
Ogun kò dà bí iyán àti ẹ̀kọ́,OGUN,WAR
àpò ògùn apa Ẹ̀fọn dára láti máa fi sùn,Ẹ̀FỌN,MOSQUITO
Máa ṣọ́ra láti bá Àbẹ̀ọ́ rìn nítorí ìwà,ASA,TALKATIVE
Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
Ago mélòó ni ìdíje náà yóò bẹ̀rẹ̀,AGO,CLOCK
Ẹ bá mi rántí mú Awò mi bọ̀ nínú yàrá,AWÒ,SPECTACLE
Fi Abó bu omi wá,Abọ́,plate
Ajá tí yóò sọnù kòní gbọ́ fèrè ọlọ́dẹ,Ajá,Dog
Ìtẹ́ Ọ̀kẹ́rẹ́ náà járọ̀ nígbà tó jábọ́,Járọ̀,To break a fall
Ìyá mi nílò Àyè tí ó gbòòrò fún ọjà wọn,ÀYÈ,SPACE
Ìwó tí o ni ilẹkùn ti o ni kọ́kọ́rọ́ ni wọ́n ki oríkì àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ naa,Ìwó,A town in osun state
Mo lọ sí ọjà ni àná,Àná,yesterday
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ta ẹyẹ ní ỌFÀ,Ọfà,catapult
Mo fẹ́ lọ sí ilé ìtọ̀ láti to,Ìtọ̀,Urine
Ẹkún ìyàwó jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú àṣà yorúbá,Ẹkún,Cry
Ọrẹ títa nínú oṣù lamulana dára púpọ̀,ỌRẸ,ALMS
Abẹ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni ìlú ìbàdàn wà,Ìlú,Village
Kunle àti Ṣọla jọ kanko asọ àrán lo s'ode,Àrán,cloth
Ọ̀rẹ́ mi àtàtà ni Kolawole àti Taofiki,Ọ̀RẸ́,FRIEND
"Ẹyin akẹ́kọ̀ọ́ mi, ẹ rí dájú pé ẹ ka àwọn ewì yín dáadáa, Ẹ̀RÁN ni ó jẹ fún yín ooo",Ẹ̀rán,Something not to forget
"Inú kò gbọ́dọ̀ bí Baba aláwò, kí ó fi ajá bọ ifá",IFÁ,god of divination
Ẹ̀KỌ̀ ẹlẹ́kọ̀ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà,Ẹ̀KỌ̀,Abandoned
Ọmọ ìlú Ọ̀la ni alaga tuntun ni ìjọba ìbílẹ̀ rẹ,Ọ̀LÀ,a town in Osun State
Ilá pele ti Ṣọla ko ni aburo baba re fi dá mọ̀,Ilà,triber mark
Ẹ̀yà ni o ma ń fi ìran kan yàtọ̀ sí òmíràn,Ẹ̀YÀ,Tribe
Ayò ọlọpọlọ gbáà ni ayò ọlọ́pọ́n,AYÒ,GAME
"À-kúkú-bí, ó sàn jù kí ènìyàn bí ọ̀dẹ̀ ọmọ lọ",Ọ̀DẸ̀,IMBECILE
idanilẹkọ yóò wáyé lọla nipa aràn,Aràn,worm
Àwọn ọmọ ile-iwe náà bu ọ̀wọ̀ fún akẹgbẹ won to se dáadáa nínú ìdíji oníléjilé,Ọ̀wọ̀,honour
ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn odẹ ló sun rárà ní bi igbeyawo,Rárà,A type of song/elegy
Àwọn ìkókó yìí kò mọ ọtun yàtọ̀ sí òsì rárá,ÌKÓKÓ,BABY
Igun ilé ni a kò àdá wa sí,IGUN,CORNER
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fi orin dà wa lára yá,Orin,music
Òkú tí o kú ni a sin sí itẹ́,Itẹ́,Burial ground
Ba mi já orín bọ̀ wá ní oko,Orín,chewing stick
Ogún ti àwọn òbí Tade fi sílẹ̀ fún un titó lo aye,OGÚN,INHERITANCE
Ẹ̀yin wo lẹ n pariwo níbè yẹn,Ẹ̀yin,Those
Iṣẹ igbà hìhun ni Ishọ̀la yan láàyò,Igbà,rope use to climb palm tree
Ọ̀lẹ ni Àlàmú kòlè kọ igba ebè l'oko,Ọ̀le,Lazy
okó ẹṣin yìí gùn ju àwọn èyí tí ó wà nínú ọgbà lọ,Okó,penis
Ẹ̀ya ti o wà ní ara rẹ̀ kọ jà ohun ti a lè fẹ nu sọ,Ẹ̀ya,Tears
Kòsí ohun ti gaga ọwọ̀ kan le se,Gaga,A piece
Ọ̀kan lára àwọn ìdí náà buru gán,Idì,Eagle
Igi ìgbá yìí so ní ọdún yìí púpọ̀,Ìgbá,locus
Ọmọ tí ó jí gègé mi nìyí,JÍ,STEAL
Kì bá dára kí o sá fún àwọn ọdaju ènìyàn yẹn,SÁ,RUN AWAY
Ǹjẹ́ kìí se aago mẹ́ta ni ẹ padà fi ìpàdé sí,AGO,CLOCK
Akin lo járọ́ ti Ṣọla pa fún wa,Járọ́,To expose a lie
Ohun tí Adé se fún àbúrò rẹ̀ burú gan,Ohun,Thing
Gbiyanju kí o lọ sí ilé ìwòsan fún iwò ojú,Iwò,spectacle
iná jó ilé náà,Iná,Fire
Oyebisi fẹ́ dé ọ̀dọ̀ àyò rẹ̀ lókè odò,ÀYÒ,FAVORITE
kí olùwà fi ìtọ́ ràn wá lọ́wọ́,Ìtọ́,Guide
Bàbá ran ọmọ ní ike ní ọjà,Ike,plastic
Iná ko jẹ ki awọn adiẹ náà gbádùn,Iná,Lice
Òdo ni Àlàmú gba nínú idanwo to ṣe,Òdo,Zero
ọ̀fà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí o gbajúgbajà ní ìpínlẹ̀ kúárà,ọ̀fà,city in kwara state
Ojo rọ̀ ni ọsẹ to kọjá,Ọsẹ,Week
Adura Bukọ́la gbà nígbà tí wọn fi ire rẹ le lọwọ,Ire,Goodness
Mo nífẹ̀ẹ́ láti ra Àgò mìíràn fún àwọn adìẹ mi,ÀGÒ,THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN
ỌSÀN tí o wà ní Orí igi náà ti pọ́n,Ọsàn,Orange
Adukẹ́ gún iyán nínú odó,Odó,Mortal
Kí ojú máa ríbi gbogbo ara lò gun rẹ̀,Ara,Body
ìwọ àti èkejì rẹ ẹ Pin ọsán yìí Àbò,Àbò,Half
Èmi ati ìyàwó fẹ́ lọ sí bi ayẹyẹ ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow
Ẹ̀re akọni ọdẹ náà wà ní ẹnu ìloro ìlú wọn,Ère,Statue
Mo dá arábìnrin náà ni oko owò,Owò,business
Eku ilé kò ṣe gba ojú bọ̀rọ̀ fún,EKU,RAT
Ike yìí mọ rẹwà púpọ̀,Ike,plastic
Mo ṣe àkíyèsí wípé àwọn Àlàmú ma ń ní ìwà púpọ̀,ÀLÀMÚ,A MALE NAME
Nínú ìjànbá ọkọ̀ to waye gaga irun ori ẹnìkan kò jona,Gaga,A piece
Dókítà òyìnbó tí gbà á ní ìmọ̀ràn pé kí ó wá gba abẹ́rẹ́ titanọọsi sí ojú egbò rẹ̀ láti dènà aburú ọjọ́ iwájú,EGBÒ,WOUND
Ẹ bá mi pé ìyá ìkókó pé mo fẹ́ rí i,ÌKÓKÓ,BABY
Ọgbọ̀n náírà ni mo ra ọsàn ẹyọ̀kan l'ọja,Ọgbọ̀n,Thirty
ọbẹ̀ ọ́yọ́ máa dùn jẹ́ ẹ̀bà tútù,Ọ́YỌ́,VEGETABLE
"Ṣọla ati awọn akẹgbẹ tó jọ kò ọ̀wọ́ rin, nígbà tí wọn jáde ile-iwe",Ọ̀wọ́,Group/ Collectively
Ìsàlẹ̀ ọrọ̀ a máa ní ẹ̀gbín ní ọ̀pọ̀ ìgbà,ỌRỌ̀,WEALTH
kínni ìdí tí Akin se n sá lọ?,Ìdí,Reason
Iṣẹ ọsẹ ni ìyá àgbà n ṣe,Ọsẹ,Soap
Fáṣítì ìjọba àpapọ̀ ti Ilé-Ifè dára púpọ̀,IFẸ̀,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
Àwọn Olórò kéde pé orò yóò jáde lọla,ORÒ,A god in Yoruba land
Ọ̀tunla ni àwọn agbagba ilé yóò pín ogún,OGÚN,INHERITANCE
ògèdè jẹ ohun tí a gbọ́dọ̀ se kí a tó wọ ìgbàlẹ̀,Ògèdè,incantation
Gbogbo Abo ni wọ́n ti ni ọkọ tán,Abo,Female
"Aya ọmọdé ni ìwà àìgbọràn pọ̀ sí, Egba sì ni ó lè le jáde",ẸGBA,CANE
Àwọn dókítà tí ṣe iṣẹ́ abẹ láti lè kó ọyún inú apá ọkùnrin náà kúrò,ỌYÚN,TUMOR
Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
Àgò ni yóò dé adìẹ gbẹyin,ÀGÒ,THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN
"IRỌ̀ pípa ni gbogbo ìgbà, kì í jẹ́ kí a nìyí",IRỌ́,LIE
Mo nílò kí alagbẹdẹ bá mi rọ ẹyá méjì lónìí,ẸYÁ,TEAR
Ìyà Àṣàkẹ́ kì í jẹ́ ọbẹ̀ ọ́yọ́ rárá,Ọ́YỌ́,VEGETABLE
Bàbá Abiodun abà arẹ̀sà kúndùn Ìfà púpọ̀,ÌFÀ,FREEBIE
Èrè ti Ṣọla jẹ lórí ọjà rẹ̀ lo fi ra asọ ọdún,Èrè,Gain/Profit
ìwọ ni o se iku pa ọmọ náà,Ìwọ,You:
Akin se àbúrò rni osẹ́,Ọsẹ́,injury
Àwọn Obí n ṣeré ní àyíká,Obí,kid/baby
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà bẹ̀rẹ̀ láti kí Ọ̀gá wọn,BẸ̀RẸ̀,BEND
Aró dà sí asọ tuntun ti mo ṣẹṣẹ rà,Aró,Dye
Ṣọla ati Bode nlọ ọjà lọla,Ọjà,market
Ẹsẹ̀ ni ọta ti ba ọdaràn náà,Ọta,Bullet
Ìgbá ti mọ ká ní àná ni mo fí ṣe irú to wa nínú ọbẹ̀ yìí,Ìgbá,locus
Ọwọ́ ni olukọ ti fún ọmọ náà lẹ́gba,Ọwọ́,Hand
Ìyá àgbà so wípé àsán ni a máa jẹ oúnjẹ alẹ́,ÀSÁN,EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT
Ogunleke ń gbìyànjú láti pá àsá abàmì náà,ÀSÁ,EAGLE
"ìyàwó burúkú dùn-ún fẹ́, àna burúkú ni o dùn-ún ni",Àna,inlaw
mi dá Ẹ̀kọ wá ní búkà,Ẹ̀kọ,Local food derived from maize
Ẹ̀kọ̀ ni ọkùnrin kọ Obìnrin nílé ọkọ,Ẹ̀KỌ̀,Abandoned
Oyè jagun nílu Feyikogbon da wàhálà silẹ,Jagun,A military title
OLÓRÍ ilé àwọn Talabi ti tẹri gba aṣọ,OLÓRÍ,LEADER
Ìyá mi àti orogún wọn nífẹ̀ẹ́ ara wọn dọba,OROGÚN,RIVAL
Ríru omi ÒKUN bo ọkò ojú omi náà mọlẹ,Òkun,Ocean
itẹ́ ni wọ́n sin àwọn òkú ṣí,Itẹ́,Burial ground
Yíyọ́ Ẹkùn t'ojo kọ́ o dábírà ni,Ẹkùn,Leopard
Bí àgbẹ̀ bá da oko dáadáa yíò rí èrè níbẹ̀,Oko,farm
Ẹ̀kún rọ́bà epo ni mo fẹ́,Ẹ̀kún,Fullness
ORÍ ni kí ẹ ma bọ kí ẹ fi òrìsà sílẹ̀,ORÍ,
Ọ̀tunla ni ọdún Ògún ni ìlú Ondo,ÒGÚN,god OF THUNDER
Olóyè Ọ̀yọ́ Aláàfin ni bàbá mi,Ọ̀YỌ́,A STATE IN NIGERIA
Ọdẹ fí ỌFÀ pa ọ̀kẹ́rẹ́ ni orí igi,Ọfà,catapult
Ọgbọ́n ọlọgbọ́n ni kìí jẹ kí a pè àgbà ní wéré,Ọgbọ́n,Wisdom
"Ṣe ọmọ náà wá sí ilé ìwé,rárá kò wá",Rárá,At all
àyà Ṣọla já nígbà tí o gburó ìbọn,Àyà,Chest
ìlú òkò jẹ́ ọ̀kan lára ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́,Òkò,A town in Oyo state
Òkùn kọni kùn ki onínú má monú,Òkùn,Darkness
Gẹ̀gẹ̀ ti Aduke ni mú kí o burẹ́wà,Gẹ̀gẹ̀,A protuberance on the neck
Àwọn ilé tí o wà ní Àjá ti wọ́n jù,Àjá,A place in Lagos
Apá kan ni ọkùnrin náà ni,Apá,Hand
Ọjọ́ ìsinmi tó ń bọ̀ ni ìsìn ìkẹyìn nínú oṣù yii,ÌSÌN,WORSHIP
Ìpínlẹ̀ Ògùn náà rẹ̀wá ni ìwọ̀nba,ÒGÙN,A STATE IN NIGERIA
Àwọn ìjọba tí ṣe àdéhùn láti san owó òógùn ojú àwọn òṣìṣẹ́,ÒÓGÙN,SWEAT
"Pakute tí mo dẹ fún ọ̀ọ́fàn, aláàmù ló mú",ALÁÀMÙ,LIZARD
"Àjọ àkọ́kọ́ tí mo dá, ní mo fi ra kẹ̀kẹ́",ÀJỌ,CONTRIBUTION
Mo fẹ́ kí a yọ sí ọ̀daràn náà ni òjijì,ÒJIJÌ,SUDDENLY
Ọ̀wẹ̀ tí mo gbà ní ọdún tí ó kọjá pé mi púpọ̀,Ọ̀wè,A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR
ikùn aláboyún naa tóbi púpọ̀,Ikùn,Stomach
Oṣù tí ó ń bọ̀ ni ìyá Ayinla máa jáde nílé opó,OPÓ,WIDOW/WIDOWER
ẹni tí ò ki ni kú ilé ó pà dànù ẹku Abọ̀,Abọ̀,welcome
Igi ọ̀pẹ ẹgbẹ̀rún kan ni a gbìn sí orí ilẹ̀ tuntun náà,Ọ̀PẸ,PALM
Ẹ̀KỌ́ ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ kọ́ ní ogbà àwọn ẹranko,Ẹ̀KỌ́,Knowledge
Ògùn yìí dára fún ojú ṣíṣú,ÒGÙN,MEDICINE
Aràrá ni olùkọ́ ède yorùbá,Ràrá,Dwarf
Ó yẹ kí gbogbo sa ipá láti dènà aburú ọjọ́ iwájú,IPÁ,ABILITY
Òpó náà kò rí Ẹsẹ̀ fi múlẹ̀ dáradára mọ oooo,ÒPÓ,PILLAR
"Ọmọ bíbí ìlú ìré ni Akinyemi, ọ̀rẹ́ Taiwo",Ìré,"A town in Osun State, Nigeria"
Ẹ gbìyànjú láti fi ilẹkun ilé sí pí padé,PADÉ,"TO SHUT, TO CLOSE UP"
Ọsẹ dúdú ni Adé fi n wẹ̀,Ọsẹ,Soap
Igi Afàrà dára fún ilé kíkàn,Afàrà,Shingle wood
Mo nílò láti kó àwo bí mẹ́ta lọ sí ilé ẹ̀kọ́,ÀWO,PLATE
Osé mẹta ni ó wà ní ilẹ̀ fún nílò ní ọdún yii,OSÉ,A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS
Ọmọ náà gbá iná mú,Iná,Fire🔥
Ẹ Funmi ni ìṣù ọkà mẹ́jọ péré,ỌKÀ,YORÙBÁ LOCAL FOOD
Bàbá Orisabunmi pa ejò isán ní ńlá kan ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá,ISÁN,A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING)
"Àáyá gbọ́n, Ògúngbè gbọ́n",Àáyá,species of monkey
"Ní òjijì, òkúta ńlá ré lu ọdẹ náà",ÒJIJÌ,SUDDENLY
Mo fi agbọ̀n kó irè oko wá lé,Agbọ̀n,Basket
"ijọ́ tí ènìyàn bá dá ẹ̀jẹ́ kìí mọ̀, àyàfi tí ìṣòro bade",Ẹ̀jẹ́,convenant
"Ajá tí yóò sọnù, kìí gbó ìfé ọdẹ",ÌFÉ,WHISTLING
Ẹ rí i dájú pé Irọ̀ ni àwọn ọmọ tí ẹ fẹ́ kó jọ fún ìdíje yìí,IRỌ̀,AGE MATE
Itan mi ti ó tóbi ni kò jẹ́ kí n le sáré dáadáa,ITAN,THIGH
kò dára kí ọmọdé máa wo òjìji ara rẹ̀,ÒJÌJI,SHADOW
Ìlù àti orin jẹ́ ọmọ ìyá kan náà,Ìlù,drum
Agbè bàbá Kọ́lá elẹ́mu tí kún fún ẹmu gidi,AGBÈ,"BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER"
Ẹ kìlọ̀ fún àwọn ọmọ yín kí wọn má fi Ògún búra èké o,ÒGÚN,god OF THUNDER
"A n t'ori Àjà jà,Àjà ní ta lọ njà lẹ́kùnlé òhun",Àjà,Roof
Ìsín ni Ìwọ̀ mi gbé wa si òkè odò,ÌSÍN,SMALL CATFISH
"Kí á má parọ́, Ìfà ni ó kó bá Fioye",ÌFÀ,FREEBIE
ỌSÁN tí ó di ìlù náà mu' jẹ́ kí ohùn dún dáadáa,Ọsán,One of the rope used to tie talking drum
Àró pa ẹran ìgbẹ́ bọ̀ l'oko,Àró,Name of person
Adìẹ ìyá àgbà ti n yé ẹyin,Ẹyin,Egg
"Ibi tí Ìfẹ́ bá wà, ohun gbogbo tí ó dára ni yóò wà níbẹ̀",ÌFẸ́,LOVE
Orílèdè náà ní lò Àbò púpọ̀,Àbò,Security
"Ọdẹ tí yóò pa ẹkùn, kò múra dáadáa ní o",ỌDẸ,HUNTER
Ilé-iṣẹ́ nla kan tun ti bẹrẹ iṣẹ ni ìlú Ọ̀tà,Ọ̀tà,"A town in Ogun State, Nigeria"
Ìlú Adà dára fún ọmọlúwàbí láti gbé,ADÀ,"A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA"
Mo fẹ́ sáré de Abẹ́ igi láti lọ ta ayò,AYÒ,GAME
Bá mi mu ìtẹ̀ wá nínú ilé,Ìtẹ́,Mat
òkò àjẹ́ ò ní bà ẹ́ tìẹ ni yíò ba àjẹ́,Òkò,stone🪨
Àwọn Ràrá wa sí orí ìtàgé fún eré àdídùn,Ràrá,Dwarf
igi Ọ̀mọ̀ wúlò púpọ̀ fún lílò,Ọ̀mọ̀,Tree of the banyan family
Mo nílò orógùn mẹta kún méje tí a rà ni ijẹta,ORÓGÙN,"TURNING STICK, TURNER"
Ayọ̀ ni orúkọ ọmọ náà,Ayọ̀,Joy
Okùn kìí gùn ko ma ní ibi tí o ti wá,Okùn,Rope
Ohùn ẹkún ọmọ náà ni mo gbọ́ tí mo fi jáde síta,Ohùn,Sound
Ọjọ ayọ̀ ni ọjọ ti mo jade ni ile-iwe gíga,Ayọ̀,Joy
Ọmọ náà pọ́n bi ọ̀lẹ̀,Ọ̀lẹ̀,Local food derived from beans(moimoi)
"Ìkokò wọlu, èèmò dé, ọ̀rọ̀ di b'òlọ yà fún mi",ÌKOKÒ,HYENA
Ogún maàkì ni ẹni kọ̀ọ̀kan yín gbọdọ̀ gbà,OGÚN,TWENTY
Igbìyànjú mi láti la ipa rere nínú ayé yìí kò ní já sí asán,IPA,PATH
Solape n fi gégé ìyá náà bú u,Gẹ̀gẹ̀,A protuberance on the neck
Àwọn esú jà nínú oko ọ̀rẹ́ mi ni ọdún tí ó kọjá,ESÚ,LOCUST
Ọmọ náà fi orí jálé agbọ́n,Agbọ́n,wasp
Ewé igi náà járọ̀ sára òwú alantakun,Járọ̀,To break a fall
Bàbá Folake sọ wípé ègbo ni òun fẹ́ jẹ,ÈGBO,FOOD DERIVED FROM MAIZE
"Ẹ̀yin tí ẹ joko sibẹ̀ yẹn, ẹ fura o",Ẹ̀yin,Those
Àyà ni bọọlu ti bá agbabọ́ọ̀lù náà,Àyà,Chest
Mo fẹràn láti máà ṣọ èdè gẹ̀ẹ́sì,Èdè,Language
Ìwé yìí kò rọrùn ni kíkà,ÌWÉ,BOOK
Ẹ ní láti ṣètò bí a ó ṣe pàdé lọla,PÀDÉ,TO COME TOGETHER
ikún jẹ ọgẹdẹ ikún n rèdí,Ikún,A kind of Squirrel
Àwọn òní agbe náà nínú ọrẹ,ỌRẸ,ALMS
"Orí igún kò ṣàdédé pá, ó ní ìtàn tó rọ̀ mọ",IGÚN,VULTURE
Ìkòkò mẹwa ló fọ níbi ìjàmbá tó ṣẹlẹ̀ lọ́nà irẹsa,ÌKÒKÒ,CLAY RESERVOIR
Adùn gé irun rẹ nitori iná orí,Iná,Lice
Ọlè wà nínú ọ̀kẹ́rẹ́ ti bàbá ọdẹ pa,Ọlẹ̀,Foetus
Wọn fi ọ̀daràn náà ṣe ẹ̀ṣín ni ojúde ọba,Ẹ̀SÍN,SHAME
Mo nílò ikàn méjì péré láti fi jẹ isu mi,IKÀN,GARDEN EGG
Mo ra asọ ní ojà laisan owó,Owó,money
Ọmọ náà sun yàrá ìyá rẹ̀ nigbati o fi ìsáná seré,Sun,To burn
Igbá tí mo fí pọn omi já sí odò lànàá,Igbá,fetcher
Olúwa bun àwọn ọkọ àti aya ní Obí tuntun,Obí,kid/baby
Ìlú Ọ̀lá ko ju mẹ́ẹ̀lì meji lo sí ìlú Ejigbo,Ọ̀LÀ,a town in Osun State
Erè wọ́ ewúrẹ́ náà mì,Erè,Snake (python)
Òdo ni ọ bẹrẹ nọ́ḿbà ẹ̀rọ aláàgbéká ti Tolu ń lo,Òdo,Zero
Kílódé tí ọ̀rọ̀ òdì jáde lẹnu rẹ,Òdì,other side of something
inú yàrá mi kò ní àyè tí ó tẹ́mi lọ́rùn rárá,ÀYÈ,SPACE
Igbó mímu ti fẹ́ yí ọmọ náà lórí,Igbó,India helm
Àwọn ikán tí ba gbogbo igi náà jé,IKÁN,TERMITE
Mo fẹràn láti máà jẹ Edé púpọ̀,Edé,Crayfish
Ìlú Ọ̀wọ̀ jé òkan lára àwon ìlú to tóbi jùlọ ní ìpínlè Ondó,Ọ̀wọ̀,A town in Ondo State
Ọ̀lẹ̀ ati ẹ̀kọ ni Ṣọla jẹ l'ọsan,Ọ̀lẹ̀,Local food derived from beans(moimoi)
Okùn agba ni bàbá fi di iṣu náà wálé,AGBA,A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST
Dókítà isegun oyinbo ti o da ìwọ́ ọmọ náà mọ iṣẹ dojú àmì,Ìwọ́,Umbilical cord
Adewale alapata nílò láti pọ́n ọ̀bẹ rẹ̀ dáadáa,Ọ̀BẸ,KNIFE
Ǹjẹ́ ìwọ ti jẹ Awújẹ rí bí?,AWÚJẸ,A TYPE OF PLANT RESEMBLE BEANS
"Taye ati Kehinde ko ga ju ara wọn lọ, ọgba láwọn méjèjì",Ọgba,Equal
Ṣé o fẹràn bàtà tí bàbá mi rà lànàá,Irú,type
Asọ àrán ni Ade wo jáde l'ana,Àrán,cloth
Kínní ipá tí ó sà lórí gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ?,IPÁ,ABILITY
Olóyè Àró n jẹ́jọ́ ni ààfin ọba,Àró,Name of person
Àwọn ẹyẹ tí fẹ́rẹ̀ jẹ gbogbo ọkà oko baami tán,ỌKÀ,GUINEA CORN
Mo ra Edé ní ọjà láti fi se ọbè,Edé,Crayfish
Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
Ògédé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní afẹ kí ó joko níbi ayẹyẹ yìí,Ògédé,Only
Nínú gbogbo ẹ̀yà tí o wà ní orílẹ̀-èdè àgbáyé ẹ̀yà Yorùbá ló dára jù,Ẹ̀YÀ,Tribe
Ilẹ̀ ti mọ kọ fún nnkan ọ̀gbìn ní ọdún yìí tó igba,Igba,two hundred
Ẹja òjìjí ṣòro láti pa púpọ̀,ÒJÌJÍ,A LOCAL NAME OF A FISH
Mo bẹ Elédùmarè kí ó ṣe mí ní olú ni orile-ede mi,OLÚ,SUPERIOR
ìgbà àti àkókò kò dúró dé ẹnìkankan,Ìgbà,Time
Àgbá òfìfo ni ó má ń pariwo,ÀGBÁ,BARREL
ìdí nì olukọ ti na Ade ni ẹgba,Ìdí,Bottom
Tẹ́tẹ́ títa tí padà gba aṣọ ni ara Ibikunle,TẸ́TẸ́,GAMBLING
Jẹ́jẹ́ lọmọ náà joko ki Ṣọla tó dọ́dọ̀ rẹ̀,Jẹ́jẹ́,Gently
Mọ wọ bàtà sí ẹsẹ̀ rẹ kí o tó jáde,Ẹsẹ̀,leg
Ẹ sọ́ra níbi fífi ògùn orí fífọ́ wo inú rírun,ÒGÙN,MEDICINE
Ǹjẹ́ mo le rí ọbẹ̀ ẹgusi díẹ̀,ỌBẸ̀,SOUP
Àdùnní gbin ewebẹ sínú ọgbà,Ọgbà,Garden
Ọ̀mọ pọ̀ láàrín ìlú láti lò,Ọ̀mọ,A builder of wall
Akitiyan olùkọ́ Adé láti rí pé ó ṣe àṣeyọrí lo padà jásí asán,ASÁN,VAIN
Ọmọ olorì àgbà ní ààfin yìí ni Adekola,OLORÌ,QUEEN
Gbogbo ìwé bàbá (D O Fagunwa) ni olùkọ́ wa sọ pé kí á rà,ÌWÉ,BOOK
Ìsìn àná dùn momi púpọ̀ gan-an,ÌSÌN,WORSHIP
Ìjọba fi rọ̀gùnrọ́gún owó sí ilé ìwé àwọn odi,Odi,dump
Mo sún fún ọ̀rẹ́ mi nítorí ìwà rẹ̀,Sún,Shift
Kò sí ohùn tí ènìyàn kò le fi àrà dá,Àrà,unique (wonder)
Ọbẹ̀ ilá ní ìyá àgbà se fún bàbá l'ana,Ilá,Okro
"Tí o bá ti jí, dákun gbìyànjú láti jí mi",JÍ,AWAKE
"Apá ọ̀tún ni ilé mi wà, ní agbègbè ojuelegba",Apá,Hand
Mo féràn láti máa fi ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ jẹ́ ẹ̀kọ,TẸ̀TẸ̀,A VARIETY OF VEGETABLE
Jẹ́jẹ́ ni òjò to rọ lana rọ̀,Jẹ́jẹ́,Gently
"Èmi pẹ̀lú olùkọ́ èdè Yorùbá, awo ni wá",AWO,SECRET
Irú bàtà wo ní o fẹ́ rà ní ọjà,Irú,type
ẸYÁ tí Ẹ̀gbọ́n mi fi ń dá ẹmu tí sọnù,ẸYÁ,TEAR
Mo ra bàtà ní ọjà lánàá,Bàtà,Shoe
"ORÍ lẹja fí n labú,ORÍ ni akàn n fí lalẹ lódò",ORÍ,
Àṣà Yorùbá wuyì púpọ̀ láwùjọ àwọn àṣà tí ó kù,ÀṢÀ,CULTURE
Ọsẹ akọkọ ni oṣù keji odun yii ni ọjọ ìbí mi,Ọsẹ,Week
Ọmọdé gbọdọ b'ọ̀wọ̀ fún ẹni tó jùú lọ,Ọ̀wọ̀,honour
Pakute bàbá ọdẹ tí pa ọ̀yà,Ọ̀YÀ,GRASS CUTTER
"Mo fẹràn ọkọ mi púpọ̀,mi o le fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ seré",Ọkọ,husband
Òjìji Olatunde ń dẹru bàá,ÒJÌJI,SHADOW
Owó ti a ná níbi ìgbéyàwó náà kò kéré,Owó,money
Kòsí ẹni tí ọ mọ bi ọlẹ̀ se n dénú alaboyun,Ọlẹ̀,Foetus
Ìfé ni a fi wa ara wa rí nínú igbó Olugbade,ÌFÉ,WHISTLING
Oyebisi kò fi ìyè sí ohun tí olùkọ́ rẹ̀ ń kọ́ ọ,IYÈ,MIND
Ìlú Òró ni a ti ní ṣíṣe lọla,ÒRÓ,"A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA"
Kúnlè sọ ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ìgbò ni imú ni ẹ̀jẹ̀ bá yọ ni imu rẹ̀,Ìgbò,headbutt
"Bámi rántí sọ fún ìyá Dosumu pé, mo nílò àdá méjì",ÀDÁ,CUTLASS
ògun aràn tun ti gb'owo lori,Aràn,worm
Ọdẹ náà pa ERÈ l'oko,Erè,Snake (python)
Igbó ti kún bo ile baba àgbà,Igbó,Bush
ẸTÙ méjì ni a ní nílé tí a ń sìn,ẸTÙ,GUINEA FOWL
Ìwọ́ we mọ ọmọ náà lọrùn nigbati ìyá rẹ̀ bí I,Ìwọ́,Umbilical cord
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ sí ilé olùkọ́ lati pọn omi sùgbọ́n wọn ò mú igbá lọ́wọ́,Igbá,fetcher
Ri dájú pé o ra ògùn fún ikun tí o mu ọ,Ikun,Mucus
Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
Olukọ ní kí ọmọ ile-iwe kọọkan mu ọwọ̀ kọọkan wa,Ọwọ̀,Broom
Awọn ọmọ ogun oril'ede yìí ṣetán láti bá àwọn agbesunmomi jagun,Jagun,To make war
"Taani òye ayé yìí yé, kí ó wá sọ",AYÉ,EARTH
ìyá ra bàtà tuntun fún ọmọ rẹ̀,Bàtà,Shoe
Ọwọ́ àwọn agbofinró tẹ ọkùnrin tó n ta igbó,Igbó,India helm
"Pátákò Ẹfọ̀n, kakaka lo má ń ta ajá lẹ́nu",PÁTÁKÒ,HOOF
Àwọn Ikán yìí nílò àmójútó gidigidi,IKÁN,TERMITE
Ọbẹ̀ ilá pẹlú gbegiri a máa dùn lórí amala,Ilá,Okro
Ní bo ìyá ìkókó gbà lọ,ÌKÓKÓ,BABY
Ìná àpà ni Kúnlè ná fún olorin,Ìná,spent
Ìlú Adà ni ìyá Rọlakẹ ti bẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀,ADÀ,"A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA"
Bàbá mí ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ní àná,Ọkọ̀,CAR
Ó ní láti gbọ́n epo ra ojú Ówo náà kí ó lè tètè dẹ̀,ÓWO,BOIL
Ọ̀gà inú ayanran mi ti sá lọ,Ọ̀GÀ,CHAMELEON
Ọ̀dẹ̀ ni gbogbo wa yóò jókòó sí lónìí,Ọ̀DẸ̀,PASSAGE
Solape ń gbìyànjú láti gba ilé-ìtajà sí bẹrẹ,BẸRẸ,"AN AREA IN IBADAN, OYO STATE"
Ma se sọ ọ̀rọ̀ òdì sí ọmọ ẹní Kejì rẹ,Òdì,other side of something
Ọmọ náà jẹun sí ikùn tí o sì yó,Ikùn,Stomach
Bàbá Atinukẹ ní oko ńlá mẹ́ta tí ó fi gbin ikàn,IKÀN,GARDEN EGG
Ìgbò ni Ṣọla fi má n bori awọn alátakọ̀ rẹ̀ nígbà tí ìjà bá wáyé-,Ìgbò,headbutt
"Ti igbó ba pọ̀ ní àyíká, o le ṣe òkùnfà ẹ̀fọn",Igbó,Bush
Awò ni àwọn dókítà fún Olabisi tí sọnù,AWÒ,SPECTACLE
Iyè ọmọ náà ti ra pẹ̀lú ibẹru,IYÈ,MIND
lọ ká ìtẹ́ tí o fi sún,Ìtẹ́,Mat
Bí a múra sí iṣẹ ọwọ ẹni oseese kìí ìṣẹ́ jìnà sí ni,Ìṣẹ́,poverty
Iwe adìẹ náà kún mi lẹ́nu púpọ̀,IWE,GIZZARD
Ọgbọ̀n ọjọ́ ni o wà nínú osù kẹrin,Ọgbọ̀n,Thirty
"Àsá tí ó gbémi ni adìẹ, kò ní pẹ́ bá ọlọ́jọ́ pàdé",ÀSÁ,EAGLE
Ìlà ti adari ayo fa silẹ ni agbaboolu naa fi'binu parẹ́ ti o fi gba kaadi pupa,Ìlà,line
Ìkòkò ìyá àgbà tí fọ́ yángá-yángá,ÌKÒKÒ,LOCAL POT
Ọmọ bíbí ìlú Ọ̀wọ̀ ni Gomina ipinlẹ Òndó àná,Ọ̀wọ̀,A town in Ondo State
Olùkọ́ àgbà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní owó láti fi ra oúnjẹ,Owó,money
jagunjagun náà fí ọ̀kọ̀ gba ara rẹ̀ lẹ ní ojú Ogun,Ọ̀kọ̀,spare
Ìlú Awó kò jìnnà sí ìlú Gómìnà,AWÓ,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
Ègbo díẹ̀ àti ẹ̀wà díẹ̀ ti tó fún un èmi,ÈGBO,FOOD DERIVED FROM MAIZE
Ogun jalumi kìí se tí ènìyàn lè gbàgbé,OGUN,WAR
"Lẹ́yìn tí a fi ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ jẹ iyán tán, bàbá àgbá pa aalọ fún un wa",TẸ̀TẸ̀,A VARIETY OF VEGETABLE
Pátákó ajúwe lo jẹ́ atọ́na láti dé ilé ìjọsìn naa,PÁTÁKÓ,"PLANT, BOARD"
Owó àjọ máa ń bo ènìyàn ní àṣírí púpọ̀,ÀJỌ,CONTRIBUTION
"Fọlákẹ́ fi ogún ẹgbẹ̀rún s'owo, o sí jẹ èrè ẹgbẹrun máàrún",Èrè,Gain/Profit
Ìsín ni ó pọ̀ jù ni odò adágún inú oko mi,ÌSÍN,SMALL CATFISH
Eré ni Ṣọla ati Dayọ nṣe ki o tó d'ija,Eré,Play/Drama
Ishola rí owó ribiribi níbi ọkà oko rẹ̀ ni ọdún yìí,ỌKÀ,GUINEA CORN
Ohun amohunmaworan rẹ ni lọ sókè ju,Ohùn,Sound
Àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ yóò yọjú sì Kábíyèsí ní òṣùpá mẹta tó ń bọ̀,Ẹ̀SÌN,RELIGION
Ọmọ náà ni ọ̀wọ́ lẹyìn,Ọ̀wọ́,Group/ Collectively
eegún tí yóò erin kò sí nígbó,Eegún,masqurade
Bí ajá bá rí olówó Re yíò ju ìrù sí,Ìrù,tail
Awọn olè se ọkùnrin naa ni osẹ́ púpọ̀,Ọsẹ́,injury
Irọ̀ ni èmi àti Adeyọde,IRỌ̀,AGE MATE
"Àgbà kì í wà lọ́jà, kí orí ọmọ tuntun kó wọ́",ÀGBÀ,ELDERLY PERSON
wakati meji ni ọkọ ayọkẹlẹ yóò lo lọnà láti ìlú ìlá sí ìlú Osogbo,Ìlá,a town in Osun state
Ará kannáà ni ìran ìbíní àti yorùbá jẹ́,Ará,related people
Orí òró ni àwọn òní janduku pa ọkùnrin náà sí,ÒRÓ,STAND
ìyàwó tí ọkọ fẹràn jù lo ń se ọbẹ̀ fún ọkọ,Ọkọ,husband
Ìlú Ìbàdàn ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ ní òpin ọ̀sẹ̀,Ìlú,Village
"Bí obìnrin bá fi ojú di orò, yóò dá ara rẹ̀ ni ẹ̀bi",ORÒ,A god in Yoruba land